Mahershala Ali
Mahershala Ali | |
---|---|
Ali at the 2019 San Diego Comic-Con | |
Ọjọ́ìbí | Mahershalalhashbaz Gilmore 16 Oṣù Kejì 1974 Oakland, California, U.S.[1] |
Orúkọ míràn | Mahershala Karim-Ali, Hershal Gilmore |
Ẹ̀kọ́ | Saint Mary's College, California (BA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2001–present |
Olólùfẹ́ | Amatus Sami-Karim (m. 2013) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | Full list |
Mahershala Ali ( /məˈhɜrʃələ/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Mahershalalhashbaz Gilmore, tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì, ọdún 1974) jẹ́ òṣèrékùnrin láti orílẹ̀-èdè Amerika. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bíi Academy Awards méjì, Golden Globe Award àti Primetime Emmy Award. Ìwé ìròyìn Times to orúkọ rẹ̀ pọ̀ mó àwọn ọgọ́rùn-ún ènìyàn tó lọ́á jù lọ ní àgbááyé, ní ọdún 2019,[2] àti 2020, The New York Times fi sípò karùn-úndínlọ́gbọ̀n lára àọn òṣèré tó lọ́lá jù lọ.[3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Ali ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì, ọdún 1974, sí Oakland, California.[4][5] Ó jẹ́ ọmọ Willicia Goines (tí wọ́n bí ní ọdún 1957) àti Phillip Gilmore (tí wọ́n bí ní ọdún 1956 tó sì di olóògbé ní ọdún 1994).[6] Wọ́n tọ́ ọ lọ́nà onígbàgbọ́ ní Hayward, California. Ìyá rẹ̀ tó jẹ́ òjíṣẹ́ Olúwa ní ìjọ Baptist ló tọ́ ọ dàgbà.[7][8][6] Bàbá rè jẹ́ eléré orí-ìtàgé tó ti farahàn nínú eré Broadway.[8][6] Maher-shalal-hash-baz jẹ́ orúkọ ọmọ kejì tí wòlíì Isaiah bí (a lè rí èyí nínú Bíbélì, nínú ìwé Isaiah, orí kẹjọ).[6]
Ilé-ìwé St. Mary's College of California (SMC) ní Moraga, California ni ó lọ, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè lọ́dún 1996 pẹ̀lú ìwé-èrí nínú mass communication.[7] Ó wọ ilé-ìwé náà pẹ̀lú ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ ti àwọn oní basketball, ó sì ń gba bọ́ọ̀lù náà lábẹ́ orúkọ "Hershal Gilmore" .[9]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gẹ́gé bí òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbogbo ènìyàn mọ Ali pẹ̀lú àpètán orúkọ rẹ̀ Mahershalalhashbaz Ali, ó lo èyí láti ọdún 2001 títí wọ ọdún 2010, nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní lo Mahershala Ali.[7][10]
Àwọn ènìyàn tún mọ̀ ọ́ látàrí èdá-ìtàn tó ṣe gégé bíi Remy Danton nínú eré Netflix tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ House of Cards, ó tún ṣe Cornell Stokes nínú Marvel's Luke Cage, ó ṣe Colonel Boggs nínú The Hunger Games: Mockingjay – Part 1 àti The Hunger Games: Mockingjay – Part 2 àti Tizzy nínú fíìmù 2008 The Curious Case of Benjamin Button, tó jẹ́ eré àkọ́kọ́ rẹ̀. Àwọn eré mìí ràn tó ti ṣe ni Predators, The Place Beyond the Pines, Free State of Jones, Hidden Figures.
Ó ti gba àwọn àmì-èyẹ Academy Award for Best Supporting Actor, SAG Award àti Critics' Choice Award àti BAFTA Award. Níbi 89th Academy Awards, òun ni mùsùlùmí àkọ́kọ́ tó gba àmì-ẹ̀ye Oscar.[11]
Gẹ́gẹ́ bí olórin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ali darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ olórin Bay Area recording label ní ọdún 2000.Orúkọ rẹ̀ sì ni Prince Ali.[12] Ní ọdún 2006, ó gbé orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, tí ń ṣe Corner Ensemble, lẹ́yìn náà, ó gbé orin mìíràn jáde bíi Curb Side Service ní ọdún 2007.[13]
Àtòjọ orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Studio albums
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Corner Ensemble (2006)
- Curb Side Service (2007)
Àtòjọ àwọn fíìmù rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù agbéléwò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2003 | Making Revolution | Mac Laslow | |
2008 | Umi's Heart | Ezra | Short film |
The Curious Case of Benjamin Button | Tizzy Weathers | ||
2009 | Crossing Over | Detective Strickland | |
2010 | Predators | Mombasa | |
Predators: Moments of Extraction | Voice role; animated short film | ||
2012 | The Place Beyond the Pines | Kofi Kancam | |
2013 | Go for Sisters | Dez | |
2014 | Supremacy | Deputy Rivers | |
The Hunger Games: Mockingjay – Part 1 | Boggs | ||
2015 | The Hunger Games: Mockingjay – Part 2 | ||
2016 | Kicks | Marlon | |
Gubagude Ko | Ochoro | Short film | |
Free State of Jones | Moses Washington | ||
The Realest Real | The Minister | Short film | |
Moonlight | Juan | Academy Award for Best Supporting Actor | |
Hidden Figures | Jim Johnson | ||
2017 | Roxanne Roxanne | Cross | |
2018 | Green Book | Don Shirley | Academy Award for Best Supporting Actor |
Spider-Man: Into the Spider-Verse | Aaron Davis / Prowler | Voice role; animated film | |
2019 | Alita: Battle Angel | Vector | |
2021 | Eternals | Eric Cross Brooks / Blade | Uncredited voice cameo in post-credits scene |
Swan Song | Cameron/Jack | Also producer | |
2023 | Leave the World Behind | G.H. | Filming |
TBA | Wildwood | TBA | Filming |
Orí ẹ̀rò-amóhùn-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2001–2002 | Crossing Jordan | Dr. Trey Sanders | 19 episodes |
2002 | Haunted | Alex Dalcour | Episode: "Abby" |
NYPD Blue | Rashard Coleman | Episode: "Das Boots" | |
2003 | CSI: Crime Scene Investigation | Tombs' Security Guard | Episode: "Lucky Strike" |
The Handler| style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A | Episode: "Big Stones" | ||
2003–2004 | Threat Matrix | Jelani Harper | 15 episodes |
2004–2007 | The 4400 | Richard Tyler | 28 episodes |
2009 | Lie to Me | Det. Don Hughes | Episode: "Do No Harm" |
Law & Order: Special Victims Unit | Mark Foster | Episode: "Unstable" | |
2010 | The Wronged Man | Calvin Willis | Television film |
All Signs of Death | Gabe | Unsold TV pilot | |
2011 | Lights Out | Death Row Reynolds | Unaired pilot |
2011–2012 | Treme | Anthony King | 6 episodes |
Alphas | Nathan Clay | 12 episodes | |
2012 | Alcatraz | Clarence Montgomery | Episode: "Clarence Montgomery" |
2013–2016 | House of Cards | Remy Danton | 33 episodes |
2016 | Luke Cage | Cornell "Cottonmouth" Stokes | 6 episodes |
2017 | Comrade Detective | Coach (voice) | Episode: "Two Films for One Ticket" |
2018 | Room 104 | Franco | Episode: "Shark" |
2019 | True Detective | Detective Wayne Hays | 8 episodes |
2020 | Race for the White House | Narrator | 6 episodes |
Ramy | Sheikh Ali Malik | 6 episodes | |
2021 | Invincible | Titan (voice) | 2 episodes |
Géèmù orí-fọ́nrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2017 | Madden 18: Longshot | Cutter Wade | [citation needed] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Viera, Bene (August 15, 2016). "Mahershala Ali Quit House of Cards and Became Marvel's New Villain". GQ. Retrieved July 12, 2020.
- ↑ Spencer, Octavia (April 17, 2019). "Mahershala Ali". Time. http://time.com/collection/100-most-influential-people-2019/5567869/mahershala-ali/. Retrieved April 17, 2019.
- ↑ Dargis, Manohla; Scott, A.O. (November 25, 2020). "The 25 greatest actors of the 21st century (so far)". The New York Times. https://www.nytimes.com/interactive/2020/movies/greatest-actors-actresses.html.
- ↑ Gutthman, Edward (December 5, 2018). "Mahershala Ali Talks About Life After Oscar the son of Phillip Gilmore". Oakland Magazine. Archived from the original on July 15, 2020. Retrieved July 12, 2020.
- ↑ Gentile, Dan (February 12, 2020). "Mahershala Ali talks BART, his favorite Bay Area restaurant and new Oakland film". San Francisco Chronicle. Retrieved July 12, 2020.
- ↑ 6.0 6.1 6.2 6.3 Galloway, Stephen (February 15, 2017). "'Moonlight' Breakout Mahershala Ali in His Own Words: A Personal Journey From Childhood Upheaval to Spiritual Awakening" (in en). The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/features/moonlight-breakout-mahershala-ali-his-own-words-a-personal-journey-childhood-upheaval-spiri.
- ↑ 7.0 7.1 7.2 Ali, Mahershala (October 22, 2011). "Mahershala Ali ('96)". Saint Mary's College of California. Archived from the original on March 2, 2019. Retrieved December 14, 2016.
- ↑ 8.0 8.1 Viera, Bené (August 15, 2016). "Mahershala Ali Quit House of Cards and Became Marvel's New Villain". GQ. Archived from the original on January 6, 2017. Retrieved January 6, 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ ESPN (February 24, 2019). "Before becoming a two-time #Oscars winner, Mahershala Ali (then Gilmore) played D-I basketball at St. Mary's from 1992-96. (via @TheUndefeated, @WCCsports)pic.twitter.com/MhHWPiY9aF". Retrieved April 29, 2019.
- ↑ Desta, Yohana (October 20, 2016). "Mahershala Ali Is Everywhere—and He's Only Getting Started". Vanity Fair. http://www.vanityfair.com/hollywood/2016/10/mahershala-ali-moonlight-luke-cage. Retrieved December 14, 2016.
- ↑ Crum, Maddie (February 26, 2017). "Mahershala Ali Becomes The First Muslim Actor To Win An Oscar". The Huffington Post. http://www.huffingtonpost.com/entry/mahershala-ali-becomes-the-first-muslim-actor-to-win-an-oscar_us_58b3866fe4b060480e0905d3.
- ↑ "'Moonlight' Oscar-Winner Mahershala Ali Used to Be a Rapper". Billboard. http://www.billboard.com/articles/columns/hip-hop/7702308/moonlight-oscar-winner-mahershala-ali-rapper-videoa.
- ↑ "Tajai Of Souls Of Mischief Talks Mahershala Ali's Days As A Rapper Signed To Hiero Imperium". HipHopDX. February 28, 2017. Retrieved March 1, 2017.